miércoles, 3 de julio de 2013

Una charla de Ogbe


ogbè wàà té k´àra ó rò wá
mo gbà, mo tè ni ìrègún ifa
difa fùn orúnmila
bàbá yòò te omo rè n´ifa
wón ní kó sákáakè, ebo ní síse
ó gbé bo ó rúbo
nígbàtí mo gbá
bàbá à mí si tè mí
àìlógbón nínú
àìmèrò níkùn
nìì mú nìì wo igbdu léèmeta
bí a bá te ifá tán
èése ti òrò èsù òdàrà fo ù ifá?
bí a bà te ifá tán
a kìí fi àjákù á gu òpe
a kìí bé ludò lái mò wè
a kìí rì iku nílè ká torí bòó
a kìí fé obìnrin awo
a kìí gba aya ìsègùn
a ò gbodò mú obìnrin aborè wole kélékélé lòó fé
olúwo eni kìí bi ni lórò ká sé
koíko tí erin gbérí mó
òrúnmila ló te akódá
ó te asèdá
ó te àràbà
òrúnmila àgbonnìrègùn olójo ibón
òun nìkan soso la òmo eni tó tèé
njé bí a bá tè mí tán
màá tùn ra mi tè
èèwò tí bá ká fun mi
màá gbó
títè la tè mi
màá tùn ra mi te o

ogbe, ven y se iniciado... LEER MAS...

No hay comentarios:

Publicar un comentario